Top Songs By Teledalase
Similar Songs
Credits
PERFORMING ARTISTS
Teledalase Ayomide Ogundipe
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Teledalase
Songwriter
Lyrics
Karanjagbon awo inu Igbo
Ijokun worowo awo odan
Mawo mawo awo ojola
Adiafun erigi alo ti o jagbon obi
Kerigi alo o to jagbon obi tan
Ifa ni ire gbogbo a maa wole toni
Ire gbogbo wole tomiwa
Ire gbogbo
Ewi falara eni o fenuyo wi temi
Eso fajero eni o fenuyo wi temi
Bire ba nbe ni waju ori mi mama sayi gbemi debe
Ire ire ire
Ewi falara, eso fajero
Enuyo, enuyo
Nitoripe áraye buru, eniyan soro oooo
Awon lan ni nwa buyo, wo nke gbanjare gbanjare
Aye lo ni nwa bumi, aye nke gbanjareeeee
Ewi falara, eso fajero
Enuyo, enuyo
Awon lan safeeri fayan
Won tun sarinako fadiye mi
Enu araye kangba, eru araye nbami oo
Enuyo, enuyo
Ewi falara eni o fenuyo wi temi
Eso fajero eni o fenuyo wi temi
Bire ba nbe ni waju ori mi mama sayi gbemi debe
Ire ire ire
Ewi falara, eso fajero
Enuyo, enuyo
Mo fenu pere si iseda mi
N o kumo oo, n o kumo oo
Emi ti foju bodu
Mo rire
Mo fire dade, Mo fire dadeee
Mo foju bodu
Ire ire ire nitemi
Ori ti nsunkun ati dade ti dade
Orin mi tiwo ejigbara ileke
Enuyo, enuyo
Ewi falara eni o fenuyo wi temi
Eso fajero eni o fenuyo wi temi
Bire ba nbe ni waju ori mi mama sayi gbemi debe
Ire ire ire
Ewi falara eso fajero
Enuyo, enuyo
Ori mi mama buru
Iseda mi mama gbabode
Fenuyo, fenuyo wi temi
Kori, Ori o ba mama gba
O ba mama gba ooo
O ba mama gba ooo
Ori o ba mama gba ooo
Writer(s): Teledalase Ayomide Ogundipe
Lyrics powered by www.musixmatch.com